Home / News From Nigeria / Breaking News / Odu Eji Ogbe – The Chant
Holy Odù Èjì Ogbè

Odu Eji Ogbe – The Chant

Ori koo da mi ‘re – Ori bless me abundantly
Orisa ma jee nsowo asenu – Orisa do not let me labor in vain
Adifa fun okankan lenirunwo Irunmole – Divinated for 401 + 1 Orisa
Nigbati won ntode orun bo wa si ode aiye
When they were to descend from heaven into the world
Ori lo koko da Orunmila si Oke-Igeti -Ori first created Orunmila in Igeti-Hills
Ori koo da mi ‘re – Ori bless me abundantly
Orisa ma jee n sowo asenu -Orisa do not le me labor in vain
Ori lo da Osun sode igede – Ori created Osun in igede town
Ori koo da mi ‘re -Ori bless me abundantly
Orisa ma jee n sowo asenu -Orisa do not let me labor in vain
Ori lo da Obatala sode Ifon -Ori created Obatala in Ifon town
Ori koo da mi ‘re -Ori bless me abundantly
Orisa ma jee sowo asenu -Orisa do not let me labor in vain
Ori lo da awon Iyami Aje sode Ota -Ori created the Iyami Aje in Ota town
Ori koo da mi ‘re -Ori bless me abundantly
Orisa ma jee n sowo asenu – Orisa do not let me labor in vain
Ori lo da Sango sode Koso -Ori lo da Sango in Koso town
Ori koo da mi ‘re – Ori bless me abundantly
Orisa ma jee n sowo asenu -Orisa do not le me labor in vain
Ori lo da Oya si ile Ira -Ori create Oya in Ira town
Ori koo da mi ‘re – Ori bless me abundantly
Orisa ma jee n sowo asenu -Orisa do not let me labor in vain
Ori lo da Ogun si ilu Ire – Ori create Ogun in Ire town
Ori koo da mi ‘re – Ori bless me abundantly
Orisa ma jee n sowo asenu – Orisa do not let me labor in vain
Ori lo da Esu si Ketu – Ori create Esu in Ketu Town
Ori koo da mi ‘re – Ori bless me abundantly
Orisa ma jee n sowo asenu – Orisa do not let me labor in vain
Ori lo da Orisa Oko si Irawo-Agba – Ori created Orisa Oko in Irawo-Agba
Ori koo da mi ‘re – Ori bless me abundantly
Orisa ma jee n sowo asenu – Orisa do not let me labor in vain
Ori lo da Eegun si ile Oje – Ori created Eegun in Oje town
Ori koo da mi ‘re – Ori bless me abundantly
Orisa ma jee n sowo asenu – Orisa do not let me labor in vain
ASE !
Ire O

Send Money To Nigeria Free

About ayangalu

x

Check Also

Ògúndá Méjì: Odù

Ògúndá Méjì.It is a fact that there is anxiety all over the World as a result of coronavirus pandemic. This is a challenge to all faiths. What else can we do other than supplication and offering. Looking at Odù, “Ògúndá Méjì, cast for today’s Òsè Ifá, Olódùmarè shall heal the World by sending out the rain. Just listen as follows:- Igún ńse dìgbóÀkàlà ńse dìgbóAdífá fún Olákanrígbò tíí se Yèyé AyéOlákanrígbò mámà jáyé ó raBó bá kù dèdè káyé ó ...