Home / Art / Àṣà Oòduà / Odu Ifa Owonrinwofun/ Ofun
opn ifa

Odu Ifa Owonrinwofun/ Ofun

| | | |
| | |
| | |
| |

 

Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o a sin ku isimi opin ose emin wa yio se pupo re laye o ase.
Odu ifa OWONRINWOFUN/OFUN lo gate laaro yi, ifa yi gba akapo ti odu ifa yi ba jade si niyanju wipe ki o bo oro daradara o ki o baa le ni okiki rere laye ki o baa si le ri aye se.
Ifa naa ki bayi wipe: Owonrin wofun wofun babalawo oro difa fun oro lojo ti oro ntikole orun bo wa sikole isalaye won ni ki oro karale ebo ni ki o wa se nitori ki o baa le ni okiki rere nile aye ki o baa si le jaye irorun, obi meji, ideregbe, igba iyan, awo obe, agbata emun oro wa kabomora oro rubo won si se sise ifa fun nigbati oro wa dele aye o wa ba awon ara inu ile aye je o si ba won mun, inu oro si dun o wa fiyere ohun bonu wipe; oun ti rubo Owonrin wofun wofun, oun ti rubo owonrin wo-fun wo-fun wo-fun.
Eyin eniyan mi, mo gbaladura laaro yi wipe inu wa yio dun dojo ale wa eledumare yio jeki a ni okiki rere nile aye o, ako si ni se alaini oun rere, ogo wa yio buyo laye aaaseee.
ABORU ABOYE OOO.

 

English Version

Good morning my people, how was your night? Hope it was greatly enjoyed, wishing you all happy weekend, may our eyes witness many more on the earth ase.
It is OWONRIN WOFUN/OFUN corpus that revealed this morning, ifa advised whoever this corpus revealed out for that he/she should feed oro very well so that he/she may have a good fame and be able to live well on the earth.
Hear what the corpus said: Owonrin wofun wofun the priest of oro cast divined for oro when oro was coming from the heaven to the earth, he was advised to offer sacrifice so that he could be famous on the earth and live conveniently on the earth, two kola nuts, goat, a calabash of pounded yam and melon soup, palm wine and he complied, when oro reached the earth he dine and wine with people, he was famed and live well, he started dancing and rejoicing praising priest the priests were praising ifa while ifa was praising God, he started shouting that; he has offered the sacrifices of owonrin wofun wofun, he has offered the sacrifice of owonrin wo-fun wo-fun wo-fun (2*).
My people, I pray this morning that we shall be living in happiness till the days of our life and God will make us have a good fame on the earth, we shall never lack any good things in our life and our glory will shine on the earth ase.

About ayangalu

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

16 Ofun Meji

Ifa: The 16 Odu Ifa & Their Meaning.

The meaning of the 16 Odu Ifa of the Ifa is based on 16 symbolic or allegorical parables contained in the 16 Core Chapters or Principles that form the basis of the Ifá, a system of divination of the Yoruba people of Nigeria. The Grand Priest of Ifa, the Babalawo or Iyanifas are the Priests and Priestesses of the Ifa Oracle that receive and decode the meaning of the Divine Messages contained in the Odu Ifa Parables that are transmitted ...