Home / Art / Àṣà Yorùbá / Ogún-l’ógbòn àwon baba ńlá ìran yorùba l’ójé alágbára, lára won ni *Timi Àgbàlé olófà iná*.

Ogún-l’ógbòn àwon baba ńlá ìran yorùba l’ójé alágbára, lára won ni *Timi Àgbàlé olófà iná*.

Timi Àgbàlé, olóde tí ó sì jé jagunjagun tí Aláàfin rán lo sí ìlú Ede láti dáàbò bo àwon ènìyàn ibè.
Alágbára ènìyàn ni Timi jé , tí a sì mò ó sí *Timi Àgbàlé olófà-iná*,gégé bí ìtàn se so, ó jé okùnrin tí ofà rè má yo Iná.

Send Money To Nigeria Free

About Awoyemi Bamimore

One comment

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

Enter Captcha Here : *

Reload Image

x

Check Also

A ya àwòrán Bola Tinubu àti Osinbajo.

   Igbékejì Ààre Osinbajo àti baba ìsàlè egbé APC Bola Tinubu ya àwòrán papò lánàá níbi fífi ìwé l’ólè tí okàn lára àwon agbenuso ilé ìgbìmò so lórí bí Ààre Buhari se n gbógun ti ìwà jegúdújerá.