Home / Art / Àṣà Oòduà / Ogún ènìyàn jàjà bọ́ lọ́wọ́ coronavirus
contain corona virus

Ogún ènìyàn jàjà bọ́ lọ́wọ́ coronavirus

Ogún ènìyàn jàjà bọ́ lọ́wọ́ coronavirus
Ìròyìn láti ọwọ́ Yínká Àlàbí


Ni ipinle Eko ni ori ti ko ogun eniyan yo ni ile iwosan ti won ti n toju awon ti kokoro Covid-19 n ba ja.


Bi o tile je pe won ni ko si oogun kan gbogi fun aisan naa sugbon Eledua n fun ipinle Eko se lati ni aseyori lori itoju awon alaisan naa. Ti a ko ba gbagbe, arakunrin omo orileede Italy ni o koko gba iwosan naa ki awon meta miiran, marun-un miiran ki mokanla to kun-un ni oni ojo keji, osu kerin odun ti a wa yii.


Ijoba apapo, ipinle ati ibile pelu ajo NCDC ni ki awon eniyan ma se dawo imototo duro ki onikaluku si gbe ile re fun igba die ki arun buruku naa le kase nile patapata.

Send Money To Nigeria Free

About ayangalu

x

Check Also

Àjo̩ NCDC mú mé̩ta nínú oògùn ìbíle̩ fún ìwòsàn covid-19

Àjo̩ NCDC mú mé̩ta nínú oògùn ìbíle̩ fún ìwòsàn covid-19Yínká Àlàbí Ajakale arun ti gbogbo eniyan ro pe ko ni pe fi orileede yii sile, lo ti ko ti ko lo mo yii. Eyi lo wa bere si ni ko gbogbo aye lominu paapaa orileede Naijiria. Awon ajo NCDC to n gbogun ti arun coronavirus pokan po lati wo bi won se le fi owo ile too. Ajo awon onisegun ibile parapo, won sin pa itu meje ti ode n ...