Home / Art / Àṣà Yorùbá / Olamide, Adekunle Gold, Praiz, Do2dtun àti Wizkid ní ibi OLIC 5.

Olamide, Adekunle Gold, Praiz, Do2dtun àti Wizkid ní ibi OLIC 5.

Olamide, Adekunle Gold, Praiz, Do2dtun àti Wizkid ní ibi OLIC 5.
Nse ni ó dàbí eni wípé àjòdún odoodún tí a mò sí OLIC 5 ti Olamide àti Wizkid papò sí ojó kan náà, tí a mò sí ojó àná, orúko àríyá odoodún náà a máa jé “Made in Lagos Concert”. Bí ó tilè jé wípé òpò rò wípé yóò fa ìjà láàrin àwon méjèjì sùgbón ó lo ní rowó rosè.
Bákan náà, Wizkid tún se eré níbi ti Olamide.
Àwòrán won nìyí ní ìsàlè.

Send Money To Nigeria Free

About Awoyemi Bamimore

x

Check Also

Òsèré obìnrin tí ó tún jé Arewà, tí gbogbo ayé mò sí Adunni Ade se àfihàn ewà ara ré nínú sòkòtò pénpé.

Òsèré obìnrin tí ó tún jé Arewà, tí gbogbo ayé mò sí Adunni Ade se àfihàn ewà ara ré nínú sòkòtò pénpé. Gbajúgbajà òsèré orí ìtàgé se àfihàn ewà rè nínú àwòrán tuntun tí ó sèsè yà, tí ó sì dàbí egbin nínú aso ìwòsún tí a mò sí pyjamas tí ó wò sókè àti sòkòtò pénpé tí ó wò sí ìsàlè, tí ó sì gbé ewà rè hàn. Ó ya àwòrán náà ní àrà òtò, tí ó sì fi ...