Home / Art / Àṣà Yorùbá / Olópàá kan ní orílè èdè Ghana fi pàsán na arábìnrin yí ní ìdí nítorí ó kò láti w’onú èwòn .

Olópàá kan ní orílè èdè Ghana fi pàsán na arábìnrin yí ní ìdí nítorí ó kò láti w’onú èwòn .

    Olópàá tí ó n sojú àgó olópàá Domping ní orílè èdè Ghana, Ase Emmanuel Osei ni won ti fi èsùn kàn látàrí wípé ó fi pàsán na arábìnrin odún mókàndílógbòn (29) tí a mò sí Sarah Darko ní ìdí látàrí ó kò láti wo inú èwon.

Send Money To Nigeria Free

About Awoyemi Bamimore

One comment

  1. LALAKUKULALA Refix

    Oye Kiwon Ran Olopa Yen Lo Si Ewon Ni.
    Iwa radarada Ni ogbeni Yii wu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

A kú osù tuntun oo.

Owó✋lá fi n sisé owó Esè la fí ñ rìnnà Olà Àtowó àtesè ki Elédùmarè má gba ìkankan nínú rè lówó wa, ká lè fi rí nñkan Ajé kó jo… Asáré pajé Arìngbèrè polà Òhun ewà ní wón jó n wòlú Adífáfún Ògbìngbìn kan Ògbìngbìn kàn Tó re inú ìrókò lo ree múlé si Tó n polówó ajé tantantan. Ó ní Alájé eni kìí la, kínú ó bínii Ñjé kí là ñ jé lótù Ifè tájé fi n yale ëni? ...