Home / Art / Àṣà Yorùbá / Omidan asewo ti se ‘kerewa’ koja sorun alakeji
Oku Ome Enyi

Omidan asewo ti se ‘kerewa’ koja sorun alakeji

Awon Yooba bo, won ni owo tada mo ni kada lehin. Iku ogun ni i pa akikanju, omi ni pada wa pa omuwe lodo. Okan ninu awon omo asewo ilu Abuja ti oruko re n je Omidan Ome Enyi lo ti se agbako iku ojiji bayii lenu ise nabi to yan laayo. Omobirin eni odun marunlelogbon (35) ni won ba oku re ninu ile itura kan to wa ni agbegbe Kubwa to wa niluu Abuja. Ome to je omo ilu Calabar lagbo wi pe oun ati okan ninu awon onibara re kan jo wole sun lale ojo Aje to koja yii fun “igbadun alailopin”.

 

Sugbon nigba ti ile yoo fi mo, oku Ome nikan ni won ba nile gelete. Okan ninu awon agbale ile itura naa lo sakiyesi oku omobirin naa ki won to gbe lo si ile igbokusi. Titi di akoko akojopo iroyin yii, enikeni ko ti le so pato iru iku to pa omidan orekelewa ti n fidi re pawo naa. Bakan naa ni ko si eni mo ibi ti onibara re fara pa mo si.

 Diesel Generators for sale

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

ile-ife riot

Omo Egbe Yoruba ati ‘OPC’ (Oodu Peoples Congress) Fajuro lori rogbodiyan ti o sele ninu ile ife

Awon omo egbe apapo-Yorùbá-titi eka –oselu, Afenifere ati awọn omo egeb (Oodua Peoples Congress), OPC, ti fariga nipa rogbodiyan ti oun lo ni ilu Ile Ife. Ninu oro kan ti abenugo fun eggbe Afenifere kán so eyi ti un se ogbeni Yinka Odumakin wipe, opolopo dukia ni o sonu ati emi awon ana ise ni won pe ati wipe pupo ninu awon ti awon agbofinro mu ni ki un se alaise aye won sọnu ni figagbaga ṣugbọn faulted aabo operatives ...