Home / Art / Àṣà Oòduà / Omoba Eze Madumere àti Chioma Rosemary kí omobìnrin kú àbò.

Omoba Eze Madumere àti Chioma Rosemary kí omobìnrin kú àbò.

    Igbékejì Gómìnà ìpínlè Imo , Omoba Eze Madumere àti aya tí ó sèsè fé, Omoba Chioma Rosemary Madumere kí omobìnrin káàbò léyìn osù méjì léyìn ìgbéyàwó, won ti bí omobìnrin. Igbékejì Gómìnà ni ó pín àwòrán yí tí ó sì se àdúrà fún omo tí ó rewà yí ní orí èro ayélujára( Facebook).

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

taniolohun

Esin Ajeji Pelu Ete