Home / Art / Àṣà Oòduà / Omo Gomina Ambode n je igbaladun Sande lowo
omo ambode

Omo Gomina Ambode n je igbaladun Sande lowo

Kosi ise lonii ojo Sande l’Alausa. Ile ni Habib Aruna, akowe iroyin fun gomina Akinwunmi Ambode, wa pelu aya re. Awon mejeeji jo n je igbaladun ara won loni miliki.Ki lo tile kan mi na lori oro oko ati iyawo oniyawo?
Eniwee, mo laiki tattoo to wa lapa ati owo madamu o. Tattoo naa fine gan-an. Eni to ba si ri Ogbeni Habib, e wi fun wi pe Olayemi Oniroyin n bo l’Alausa lola fun awon oro to se pataki.

About admin

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

ambode

Gov. Ambode sacks Folarin-Coker and two other commissioners

Today, Lagos State Governor, Akinwunmi Ambode, effected a reshuffle of his cabinet, with the dropping of the Commissioners for Tourism- Mr. Folorunsho Folarin-Coker; Finance, Dr. Mustapha Akinkunmi and Transportation, Dr. Ekundayo Mobereola. Crdt: The Nation