Home / Art / Àṣà Oòduà / Omokùnrin odún méèédógún tí orúko rè ńjé Okorogheye David ni ó peregedé jùlo nínú ìdánwò àsekágbá ti ilé-èkó

Omokùnrin odún méèédógún tí orúko rè ńjé Okorogheye David ni ó peregedé jùlo nínú ìdánwò àsekágbá ti ilé-èkó

Omokùnrin odún méèédógún yí gba máàkì tí ó pò jùlo nínú ìdánwò àti wo ilé-èkó gíga ifáfitì tí ó sì gba púpò jùlo nínú WAEC.

Omokùnrin yí gba àmì A nínú gbogbo ìdánwò tí Ó se fún WAEC tí Ó sì gba jùlo nínú ìdánwò Jamb tí ó gba 332 nínú èsì rè. Èyí wuyì púpò.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

taniolohun

Esin Ajeji Pelu Ete