Home / News From Nigeria / Breaking News / Opepe aye Ifa dun opepe !
araba ifa sermon

Opepe aye Ifa dun opepe !

Please sing along with me as follows :-

Opepe aye Ifa dun opepe
Nijo eku eleku Opepe, eleku o gbodo rojo opepe
Nijo eja eleja Opepe, eleja o gbodo sunkun Opepe
Nijo eye eleye Opepe, eleye o gbodo rojo opepe
Nijo eran eleran Opepe, eleran o gbodo rojo opepe
Aye ifa dun Opepe

Opepe(praise name), Ifa has enjoyable life
When it demands dry rat, the owner of rat must never complain
When it demands dry fish, the owner of fish must never cry
When it demands birds( pigeon, fowl, rooster, guinea fowl, duck etc), the owner of birds must never complain
When it demands for animals( goat, ram, sheep, cow etc), the owner of animals must not grumble
Opepe (awesome), don’t you see Ifa enjoys goodness.

Babalawo, the righteous and dedicated ones should be happy for having Ifa.

Happy Ose Ifa today to you all.

Stay blessed

From Araba of Oworonsoki land, Lagos Nigeria.

Send Money To Nigeria Free

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Gómìnà Akínwùnmí Àmbọ̀dé ju ọwọ́ lu òfin

Gó́mìnà Ìpínlẹ̀ Èkó, Akínwùnmí Àmbọ̀dé ju ọwọ́ lu òfin fún ìpamọ́ àti ìgbéga èdè Yorùbá

Aàrẹ Ọ̀nà Kakanfo, Ọ̀túnba Gàní Adams ti wọn ṣe ìwúyè fún ni ọjọ́ Àbámẹ́ta, oṣù kini, ọjọ́ kẹtàlá ọdún Ẹgbàáléméjìdínlógún fi ẹ̀dùn ọkàn hàn nipa bi àṣà àti ìṣe Yoruba ti fẹ́ parẹ́.  Nigba ìwúyè, Ọ̀túnba Gàní Adams ṣe àlàyé pé́ ori ire ni wi pé kò si ogun ti ó nja ilẹ̀ Yoruba lọ́wọ́lọ́wọ́, ṣùgbọ́n òhun yio tẹra mọ́ṣẹ́ lati dáàbò àti bójútó àṣà àti ìṣe Yorùbá. Ìpínlẹ̀ Èkó ti tún ta wọ́n yọ lẹ́ ẹ̀kan si.  Ni Ọjọ́bọ̀, ...