oriki ori

Oriki Ori

Ori Onise Apere Atete gbeni ju Orisa Ori atete niran Ori lokun Ori nide Ko si Orisa ti dani gbe leyin Ori eni Ori ni seni ta a fi dade owo Ori ni seni ta a fi tepa ileke woja Ori ni seni ta a fi lo mosaaji aso oba Ori gbe miOri la mi Ori ma pada leyin miOri, the competent Creator
Apere
He who is faster in aiding one than the Orisa
He who instantly remembers his devotee
Ori is valuable
Ori is jewelry
No Orisa can favour one without the consent of one’s Ori
It is Ori that aids one for one to be crowned of money
It is Ori that bless one for one to be using beaded walking stick even to the market
It is Ori that bless one for one to be using valuable cloths
Ori, please, support me
Ori, please, bless me
Ori, please, never turn against me.

More on ORI:

What is Ori?

Ori is the “Head”. Ori is an Orisa, and a very powerful and important one.
Odu Ifa Ogunda Meji teaches us:
Ko s’orisa ti i da ni i gbe lehin ori eni
No Orisa helps an individual without the consent of his or her Ori.
Also in Odu Ifa Ogunda Meji, IFA teaches us that Ori is the only Orisa that can be with us and accompany us through all of life’s journeys.
Odu Ifa Irete Ofun teaches us:
Ko si Orisa to to nii gbe
Leyin Ori eni
Ori gbona j’Orisa
No other Orisa can give support
Outside of one’s Ori
Ori is higher than all Orisa.
Ase
We are born with Ori, but we also can (and should) receive the physical shrine for Ori. Receiving Ori is a very powerful ceremony. Receiving Ori helps align one with their inner.
ASE ASE ASE ASE ASE…

Happy new week

Send Money To Nigeria Free

About ayangalu

x

Check Also

Governor Seyi Makinde

Màá ṣa ipá láti mú káwọn aráàlú nígbẹkẹ̀lé nínú ìjọba – Seyi Makinde

Màá ṣa ipá láti mú káwọn aráàlú nígbẹkẹ̀lé nínú ìjọba Fẹ́mi Akínṣọlá Àwọn àgbà bọ̀,wọ́n ní ,bí Ọlọ́run bá rí ọ, jéèyàn náà ó sẹ̀ríìrẹ,bẹ́ẹ̀ gẹ́lẹ́ lọ̀rọ̀ rí,bí Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Onímọ̀ ẹ̀rọ Seyi Makinde ti fọwọ́ gbáyà pé òun yóó sa gbogbo ipá òun láti rí i dájú pé àwọn èèyàn rere ìpínlẹ̀ náà ní ìgbẹ́kẹ̀lé kíkún nínú Ìjọba òun. Gómìnà Makinde fi ọwọ́ idaniloju ọ̀hún sọ̀yà nínú ọ̀rọ̀ apilẹkọ rẹ̀ níbi ìpàdé ìta gbangba lórí ètò ìṣúná ọdún ...