sango

Oríkì Sango

 

(Praising the Spirit of Lightning)

Kawo Kabiyesile, etala mo júbà, gadagba a júbà. Oluoyo, Etala mo júbà, gadagba a júbà. Oba ko so, etala mo júbà, gadagba a júbà. Ase.

Hail to the Chief, It is thirteen times that I salute you. Chief of Oyo, It is thirteen times that I salute you. The Chief who has not died, it is thirteen times that salute you. May it be so.

ORÍKÌ OSUN

(Praising the Spirit of the River)

Iba Osun sekese, Làtojúku awede we mo. Iba Osun Olodi, Làtojúku awede w e mo. Iba Osun ibu kole, Làtojúku awede we mo.

Praise to the Spirit of Mystery, Spirit who cleans me inside out. Praise to the Spirit of the River, Spirit who cleans me inside out. Praise to the Spirit of Seduction, Spirit who cleans me inside out.

Yeye kari, Yeye’jo, Yeye opo, O san réré o. Mbè mbè ma

yeye, mbè mbè l’oro. Ase.

Mother of the mirror, Mother of dance, Mother of abundance, we sing your praises. Exist, exist always mother, exist always in our tradition. May it be so.

Babalawo ogunbanwo Alani

Send Money To Nigeria Free

About ayangalu

x

Check Also

Happy Ose sango!

Igba ara lanbura enikan kinbu sango lerun adifafun olukoso laalu arabambi Omo arigba ota Segun onbelarin ota onfi ojo jumo konminu ajogun. Tani Peri oba to oo Emi oo operire alade..Sango yiobawa Segun gbogbo Otawa aori tiwase.. Happy Ose sango,sango will blessed us. Ase Edumare.. AWO OSA LOGBE.