Home / Art / Àṣà Yorùbá / Purity Okojie se ayeye ojó ìbí rè nígbà tí ó pé omo odún méfà (6) ní àná: Mercy Johnson se ayeye ojó náà lo.

Purity Okojie se ayeye ojó ìbí rè nígbà tí ó pé omo odún méfà (6) ní àná: Mercy Johnson se ayeye ojó náà lo.

Akoni àti ogbóntàrigì òsèré obìnrin, tí a mò sí Mercy Johnson Okojie, tí ó fé omo oba Odi Okojie tí ó sì bí omo méta, Okúnrin kan obìnrin méjì. Mercy Johnson ti se ayeye ojó ìbí fún àkóbí rè, orúko omo báà a máa jé Purity, ó sì ti pé omo odún méfà.
Láti se ayeye náà fún omo rè, Mercy Johnson pin sí orí èro ayélujára ínsítágìràmù láti pín àwòrán omo rè tí ó rewà.
Ó ko síbè wípé:
“Odún méfà séyìn, ojó Àìkú gangan ni mo bí Purity àti wípé ó pé omo odún méfà ní òní. Farabalè…ó ti gba àyè gbogbo ènìyàn lóókan àyà mi súgbón ko séni tí ó le gba àyè re lóókan àyà mí, ìyá re ní’fé reju ayé rè lo…
Èyin òré, purity wa ti pé odún méfà lónìí.”

Send Money To Nigeria Free

About Awoyemi Bamimore

x

Check Also

ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ OLÓÒGBÉ OLÓYÈ OLÁDÈJO ÒKÉDÌJÍ.

ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ OLÓÒGBÉ OLÓYÈ OLÁDÈJO ÒKÉDÌJÍ. Ìdílé onígbàgbó ni Olóyè Oládèjo Òkédìjí ti wá. A bí i ní ìlú òyó, tíí se ìlú bàbá rè ní ojó kerìndínlógbòn, Osù kewàá odún 1929. Òun ló sìkejì omo méta tí ìyá àti bàbá rè bí. Ìlú òyó ni Oládèjo Òkédìjí ti lo ìgbà èwe rè. Nígbà tí ó di omo odún méfà ni ó bèrè ilé-ìwé. Ó lo sí ilé-ìwé ìjo elétò ti Àpáàrà, òyó, láàrin odún 1935 sí 1941. Ó ...