Home / Art / Àṣà Oòduà / Sangbafo! Won Ge Apa Ati Ori Arakunrin Kan Nitori Ija Ile Ni Ipinle Delta
delta

Sangbafo! Won Ge Apa Ati Ori Arakunrin Kan Nitori Ija Ile Ni Ipinle Delta

Ajalu ti o n sele lowo ni amai ati umuebu ni agbegbe iwo oorun ni ijoba ibile ndokwa ti owa ni ipinle delta – o ti gba ona iburu nipa pipa odomokunrin kan ti won ge apa ati ori re nitori ija ile. Ajalu ti o ti n sele lati ojo pipe ti opolopo eniyan si ti fara kaasa (farapa) ti opo ti gba ibe rorun ti ijoba o si gbe igbese lori re….

 

English Version

Continue after the page break

Send Money To Nigeria Free

About ayangalu

x

Check Also

Ọdún orò gbìnà yá, ìdájí ní àwọn olórò yóò fi máa yíde ìlú níṣẹ̀yin

Fẹ́mi Akínṣọlá Ṣe aifẹsọ kebosi,lai rẹni jo o,ati pe n ta o ba fẹ o bajẹ,o ni bi o ṣe yẹ ka ṣe e,eyi lo bi atunse abẹnu lati fopin sawuye wuye to waye latari aawọ to suyọ laarin awọn onisese ati awọn ẹlẹsin meji ti o ku(Kitẹẹni ati Musulumi).Wayi o, igbakeji alaga fun ẹgbẹ agbaagba nilu Isẹyin, Alhaji Bọlaji Kareem, ti kede pe ija ti dopin, ogun si ti tan lori aawọ ọrọ sise nilu Isẹyin.Kareem, ẹni to soju ...