Home / Art / Àṣà Yorùbá / Sola Sobowale dàbí egbin bínú aso tí ó wo lo síbi ìfilólè eré orí ìtàgé tí àkolé rè n jé “King of Boys.

Sola Sobowale dàbí egbin bínú aso tí ó wo lo síbi ìfilólè eré orí ìtàgé tí àkolé rè n jé “King of Boys.

Sola Sobowale dàbí egbin bínú aso tí ó wo lo síbi ìfilólè eré orí ìtàgé tí àkolé rè n jé “King of Boys.
Ògbóntarìgì tí ó tún jé gbajúgbajà òsèré tí gbogbo èèyàn mò sí Sola Sobowale, wo aso aláràbarà lo síbi ayeye ìfilólè eré orí ìtàgé tí àkolé rè n jé ” Kings of Boys”.
Aso alésepò mó sòkòtò tí àwon olóyìnbó n pè ní Jumpsuit tí ó sì tún dàbí kaaba ni ó wò tí ó sì tún dàbí sisi nínú rè.

Send Money To Nigeria Free

About Awoyemi Bamimore

x

Check Also

Ballot Boxes Destroyed As Armed hoodlums Storm Polling Unit In Lagos. Photos/Video

Pandemonium broke out moments ago in Amukoko, Ajeromi Ifelodun local government area of Lagos State, after thugs stormed a polling unit to disrupt the ongoing presidential and national assembly elections. According to Emmanuella Okoye who reported the incident, hoodlums stormed the polling unit in with bikes and tricycles (Keke Napep) while carrying metals, sticks and other weapons. The hoodlums chased people out of the polling unit and destroyed ballot boxes and other election materials. Watch the video below.