Home / Art / Àṣà Yorùbá / Ti eba jabo si inu omi pelo ọkọ ayọkẹlẹ: Eleyi ni ona irọrun ti elefi gba emi yin la (Fidio)
asa yoruba

Ti eba jabo si inu omi pelo ọkọ ayọkẹlẹ: Eleyi ni ona irọrun ti elefi gba emi yin la (Fidio)

Eleyi ni ona irọrun ti elefi gba emi yin la, ati ligba ti eba jabo si nu omi eyin ati ọkọ ayọkẹlẹ yin. A se iwadi wipe egbelegbe irinwo “400” awon eniyan ni ounku ni ododun lipa ijamba awon ati ọkọ ayọkẹlẹ won kiko si nu odo, ase iwa di wipe opolopo awon eniyah ni won ma un wole pelu oko ayokele na.  Eyii ni oun ti e ne se lati yo ara yin ninu ewu na, na i pe egbe omo ogun panapana tabi olopa, nipa wiwo fidio ti o wa ni sale oro yi, yi o je anfani fun yi nigba ti isele na ba se si yin.

 

English Version

Continue after the page break.

Send Money To Nigeria Free

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

Enter Captcha Here : *

Reload Image

x

Check Also

asa yoruba

Oríkì Àjọbí, Àṣà Yorùbá ti ó Nparẹ́ lọ

Oríkì* jẹ ọ̀rọ̀ ìwúrí ti Yorùbá ma nlò lati fi sọ ìtàn àṣà àti ìṣe ìdílé lati ìran dé ìran. Ninú oríkì ni a ti lè mọ ìtàn ìṣẹ̀dálẹ̀ ẹbí ẹni àti ohun ti a mọ ìdílé mọ́, bí i irú iṣẹ ti wọn nṣe ni ìdílé, oriṣiriṣi èdè ìbílẹ̀ Yorùbá, oúnjẹ ti wọn njẹ àti èyí ti wọn ki i jẹ, ẹ̀sìn ìdílé, àdúgbò ti wọ́n tẹ̀dó si tàbi ìlú ti a ti ṣẹ̀ wá, àṣeyọrí ti wọn ti ...