Recent Posts

Best Reviews

Naija Gist

Local News

Entertainment Gist Nigeria

  • wizkid tiwa malo
  • gene
  • Review-Alabi Bi Esu - Complete anti-Yoruba Tradition and A Racist Ideology Against Oodua People
  • Tacha
  • dangote

The Buzz Central

News From Nigeria

nlc

Àfikún owó oṣù nìkan lẹ̀rọ̀ ìyanṣẹ́lódì- NLC

Àfikún owó oṣù nìkan lẹ̀rọ̀ ìyanṣẹ́lódì…NLC Fẹ́mi Akínṣọlá Ẹgbẹ́ òṣìṣẹ́ lorilẹede Nàìjíríà, NLC, ti sọ fún àwọn adari ẹgbẹ́ ọhun láwọn ipinlẹ pé kí wọ́n gbaradi fún ìyanṣẹ́lódì, bẹrẹ láti ọjọru, ọjọ Kẹrindinlogun oṣù Kẹwàá ọdún 2019.Ẹgbẹ́ NLC ní òun yóò gunle iyaṣẹlodi náà tí ifọrọwerọ oun pẹlu Ìjọba àpapọ̀ kò bá so eso rere. Nínú atẹjade kan tí ẹgbẹ́ náà fi sọwọ sí àwọn ẹka rẹ̀ ní àwọn ipinlẹ, ti akọwe àgbà ẹgbẹ́, Emmanuel Ugboaja fọwọ si, lóti sísọ ...

Read More »

Àyájọ́ ‘Má wọ kọ́mú’

Àyájọ́ ‘Má wọ kọ́mú’ ló kò yìí, kín làkíyèsí ẹ̀yin obìnrin lórí àìsàn jẹjẹrẹ ọyàn Fẹ́mi Akínṣọlá Ọjọ́ Kẹtàlá oṣù Kẹwàá ọdọọdún ni àyájọ́ ọjọ́ ‘Má wọ kọ́mú’ lorilẹede Nàìjíríà eyi tó ń sọ fún àwọn obìnrin láti bá kọ́mú yan odì lọ́jọ́ náà. Gẹ́gẹ́ báa ṣe mọ̀ oṣù Kẹwàá yìí kan náà ní àwùjọ àgbáyé yà sọ́tọ̀ fún àyájọ́ gbígbógun ti àìsàn jẹjẹrẹ ọyàn, lọ́wọ́-lọ́wọ́ báyìí, orí ayélujára ti kún fún àwòrán awọ̀n obìnrin tó ń yan kọ́mú lódì ...

Read More »

Ìjọba ṣe tán láti bẹ̀rẹ̀ sí ní gbowó orí lóri ìbáraẹnisọ̀rọ̀

Ìjọba ṣe tán láti bẹ̀rẹ̀ sí ní gbowó orí lóri ìbáraẹnisọ̀rọ̀ Fẹ́mi Akínṣọlá Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àbùùbùtán oore lọ̀rọ̀ sísọ jẹ́ ,fáwa ọmọ aádámọ̀,ọ̀làjú àsìkó yìí,ti fẹ́ mú kí nǹkan ó gbọ̀nà ọ̀tun yọ,bí ó ti jẹ́ pé ọ̀gọ̀ọ̀rọ̀ àwọn ọmọ orílẹ̀èdè yìí yóò máa same lórí ìpè e won.Álága ilé iṣẹ́ tó ń gbowó orí lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà (FIRS), Babatunde Fowler ti ní báyìí o, kò sí nǹkan tó buru nínú kí ìjọba máá gba owó orí fún ...

Read More »

Yẹ Kí Nàìjíríà Dín Iye Àwọn Sẹ́nétọ̀ Tó Ń Ṣojú Wọn Kù Tàbi, Ka Kúkú Pa Ipò Náà Rẹ́ – Fayemi

Ó yẹ kí Nàìjíríà dín iye àwọn Sẹ́nétọ̀ tó ń ṣojú wọn kù tàbi, ka kúkú pa ipò náà rẹ́ …..Gomina ìpínlẹ̀ Ekiti Fẹ́mi Akínṣọlá Ó ní àwọn sẹ́nétọ̀ tí ń náwó tó pọ̀jù léyìí tí Ìjọba yí le fi owó náà ṣe nǹkan mìíràn fáwọn ará ìlú.Ó gba Ìjọba nímọ̀ran láti ṣàmúlò àbọ ìwádìí àwọn ìgbìmọ̀ Orosaye Stephen.Àbọ ìwádìí Orosaye ni pé kí wọ́n da àwọn iléeṣẹ́ Ìjọba àpapọ̀ tí iṣẹ́ wọ́n jọra pọ̀ di ọ̀kan ṣoṣo kí wọ́n ...

Read More »

Latest World News