Recent Posts

Best Reviews

Naija Gist

Local News

Entertainment Gist Nigeria

  • mayd
  • tiktok
  • lagbaja unmasked
  • Yoruba double demon
  • duduke
  • Who dies first
  • yomi

The Buzz Central

News From Nigeria

Akeredolu

È̩yin òsìsé̩ mi nílò àyè̩wò coronavirus kíákíá- Akeredolu

È̩yin òsìsé̩ mi nílò àyè̩wò coronavirus kíákíá – Akeredolu Arakunrin Rotimi Akeredolu ti o je gomina ipinle Ondo lo n gba awon alabasise re niyanju ki won fi oro ti oun se arikogbon. O ni iba lasan ni o se oun ti oun si se itoju ara laarin ojo meji pere. O ni leyin re ni awon ore gba oun nimoran lati se ayewo ajakale arun coronavirus. Gomina naa ni “iyan jija lo n ba ore je” oun se ayewo ...

Read More »
ncdc

Àwo̩n aké̩kò̩ó̩ ti lè wo̩lé, mótò ti lè rìn làti ìpínlè̩ sí ìpínlè̩ – NCDC

Àwo̩n aké̩kò̩ó̩ ti lè wo̩lé, mótò ti lè rìn làti ìpínlè̩ sí ìpínlè̩ – NCDC Ijoba apapo ti fowo si aba ti awon ajo NCDC gbe lo si odo Aare. Ijoba fi aaye sile ki awon ara ilu maa rin maa yan fun ose merin miiran. Ni eyi to maa tun je ki won mo odo ti won maa da orunla si. Ijoba apapo si salaye pe isede naa wa ni awon ijoba ibile mejidinlogun kaakiri orileede yii. Won ni ...

Read More »
Festus Keyamo

Keyamu àti àwo̩n Asojú sòfin tutó̩ sí ara wo̩n lójú

Keyamu àti àwo̩n Asojú sòfin tutó̩ sí ara wo̩n lójú Minisita fun ipinle ati eto ise ni orileede yii, Agbejoro agba Festus Keyamu ni awon Asoju sofin ranse si ni ilu Abuja lonii. Won fi saarin, won si bere si ni da ibeere lorisiirisii boo lori ibi ti ise de duro lori osise egberun kan fun ijoba ibile kan. Ijoba ibile ti o wa ni orileede yii je egberin din merindinlogbon (774). Keyamu ni ona ise naa ti jin, awon ...

Read More »
syria

Russian Private Military Contractors Took Control Of Libya’s Largest Oil Field

Washington is concerned by the growing Russian influence in Libya as Turkish-led forces are preparing to storm the port city of Sirte, controlled by the Libyan National Army. On June 26, the US embassy in Libya released a statement claiming that it condemns a “foreign-backed campaign to undermine Libya’s energy sector and prevent the resumption of oil production.” The statement said that the US shares the “deep concern” of the National Oil Corporation affiliated with the Turkish-backed Government of National ...

Read More »

Latest World News