Home / Art / Àṣà Oòduà / Amosun se ileri ipe ofe ori foonu fun awon osise lodun 2016
amosun

Amosun se ileri ipe ofe ori foonu fun awon osise lodun 2016

Ijoba ipinle Ogun, labe akoso Senator Ibikunle Amosun, ti se ileri ipe ori foonu ofe fun gbogbo awon osise ipinle naa lodun tuntun 2016 to wole de yii.  Igbese tuntun yii ni olori eka imo ero ati ibanisoro, Ogbeni Olatundun Adekunte fi da awon oniroyin loju lojo Isegun to koja yii.

Gege bi alaye re, ile ise ijoba to wa ni Oke-Mosan ni won yoo gbe ero ti yoo fun awon osise ni anfaani lati le pe ipe ofe lori foonu si. Awon akoko ti won ba si wa ni enu ise ni kan ni won yoo ni anfaani lati lo ipe ori foonu ofe naa. Eleyii ti ijoba gbagbo wi pe yoo mu won jafafa lenu ise won gbogbo.

“Bi o tile je wi pe iru eto yii ti wa nile tele ni ile ise ijoba ipinle Ogun, sugbon fun awon kan pato ni. Nibayii, bere lati odun 2016, gbogbo osise pata ni yoo beere si i je afaani ipe ofe naa ni yalayolo,” Adekunte fi kun oro re bee

Yato si eleyii, o ni ijoba yoo tun se gbogbo akitiyan lati ri wi pe ilo ero ati ayelujara di irorun fun awon eniyan ti won gbe ni igberiko. Eleyii ti yoo fun won ni anfaani lati mo nipa awon eto ijoba ati lati je alabapin ninu isejoba awarawa to wa lode.

Orisun: olayemioniroyin

Send Money To Nigeria Free

About admin

x

Check Also

amosun

APC’s Amosun Wins Ogun State Governorship Election

Ibikunle Amosun of the All Progressives Congress, APC, has been declared winner of the 2015 elections in Ogun State. The INEC Returning Officer who announced the result in Abeokuta, the state capital, said Mr Amosun clinched 306,988 votes closest to his opponent, Mr. Gboyega Isiaka of the PDP who had 201,440 votes. This is the first governorship result to be announced. In Imo State collation is still on going, while in Kaduna State, INEC has been announcing results from different ...