Home / Art / Àṣà Oòduà / Sofia Kenin gba ife è̩ye̩ ìdíje Australia open 2030
Sofia Kenin

Sofia Kenin gba ife è̩ye̩ ìdíje Australia open 2030

Omo orileede American, Sofia Kenin, ti fi ebun re han si gbogbo agbaye pelu bi o se bori ifigagbaga asekagba laarin oun ati omo orileede Spain, Garbine Muguruza pelu ami ayo 4-6 6-2 6-2 ni Melbourne lati gba ife eye idije naa ti abala awon obinrin.

Eyi ni igba akoko ti Garbine, odun mokanlelogun, yio gba ife eye naa leyin igba mejila otooto ti o ti n kopa sugbon Muguruza ti gba ife eye naa ni igba meji otooto.

Kenin ni agba eyin orile obinrin ti okere julo lati gba ife eye Australia Open leyin ti omo orileede Russia, Maria Sharapova ti gba ni odun 2008.

Se Yoruba ni won so wipe inu eni o ki fun ki a pa mora ! Kenin, eni ti o je wi pe baba re ni olukoni re, le opa igba eyin orile re mole ti o si fo mo baba lorun lati fi idun re han si aseyori alailegbe naa.

Send Money To Nigeria Free

About ayangalu

x

Check Also

Àwọn Fíìmù Òde Òní Ń Kọ́mọ Lólè Àti Ọ̀pọ̀ Ìwà Burúkú – Iyabo Ogunsola

Àwọn Fíìmù Òde Òní Ń Kọ́mọ Lólè Àti Ọ̀pọ̀ Ìwà Burúkú – Iyabo Ogunsola

Àwọn fíìmù òde òní ń kọ́mọ lólè àti ọ̀pọ̀ ìwà burúkú Fẹ́mi AkínṣọláṢé àwọn àgbà bọ̀ wọ́n ní ẹgbẹ́ burúkú ba ìwà rere jẹ́. Ajíyìnrere Felicia Iyabode Ogunsola tí gbogbo èèyàn mọ̀ sí Efúnsetán Aníwúrà, Ìyálọ́de ìlú Ìbàdàn nínú eré, ti kìlọ̀ fáwọn òṣèré tíátà láti dẹ́kun àṣà ṣíṣíra sílẹ̀ nínú fíímù. Efúnsetán ní àṣà burúkú gbáà ni.Ó ṣàlàyé pé kìí ṣe ohun tó dára kí àṣírí ọyàn máa hàn síta,iṣẹ́ Èṣù ni. Ó fikún ọ̀rọ̀ rẹ̀ pé kò sí ...