Home / Tag Archives: Àṣà Yorùbá (page 7)

Tag Archives: Àṣà Yorùbá

Cee C jáde pèlú Uriel àti Craze Clown ní Dubai .

Cee C jáde pèlú Uriel àti Craze Clown ní Dubai . Àwon ará ilé BBnaija télè, Cee C àti Uriel ya àwòrán papò pélù Craze Crown ní orílè èdè Dubai. E wo àwòrán àwon àwom métèta tí ó rewà púpò ...

Read More »

Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbéyàwó olùwòsàn tí ó tún lóyún sínú àti oko rè tó jé Engineer.

Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbéyàwó olùwòsàn tí ó tún lóyún sínú àti oko rè tó jé Engineer. Olúwòsàn tí ó tún lóyún sínú àti oko rè tí ó jé Engineer ti pín àwòrán kí ó tó di ojó ...

Read More »

Àwòrán omo odún mókàndínlógún (19) tí won mú pèlú orísirísi èyà ara ní Awka.

Gégé bí ìròyìn se so, won ti fi ìgò gún omo odún mókàndínlógún (19) yánmayànma látàrí àwon èyà ara tí won bá ní owó rè, won bá omoníka àti ojú ara omo odún mérin okùnrin ní Awka, ìpínlè Anambra. Afura ...

Read More »

Tonto Dikeh se tán láti se isé abe láti tún ara rè dá.

Tonto Dikeh se tán láti se isé abe láti tún ara rè dá. Gbajúgbajà àti ìlú mòóká òsèré tí a mò sí ìyá ìjo, Tonto Dikeh, ti gbe lo sí orí èro ayélujára Ínsítágírámú láti jé kí ámò wípé nse ...

Read More »

KÁDÀRÁ Ò GBÓÒGÙN

Adáni wáyé ti dáni sáyé ná. Káwayé máyà tó sayé dàwáàlọ. Òréré layé kò see wò tán. Àyàfi ká gba kádàrá lókù. Kádàrá ò seé kọ̀ láìgbà. Ádíá f’ẹ́ja tó f’ibú selé. Ádíá f’ọ́pọ̀lọ́ tó f’òkè s’ebùgbé. Ọ̀pọ̀ló f’omi s’elé, ...

Read More »

Olódùmarè mà tóbi lóba ooo.

Olódùmarè mà tóbi lóba ooo. Kíni olórun olódúmarè kò le se tán, Olódùmarè tó dá ayé òhun òrun tí ó sì so òrò sí órìlè ayé, òrò náà á máa jé Ifá tí ó fi rán òrúnmìlà baba àgbónìrègún. Òdú ...

Read More »

Olorì Basirat tí ó pé odún mókàndínlógún ni ojó mélòó séyìn ya àwon àwòrán tí ó wuyì.

Olorì oba àti ìyá ìbejì ni a gbó wípé ó máa n dá oba lóhùn láàfin àti wípé òhun ni ó máa n pèsè gbogbo nkan tí Kábìèsí fé láàfin àti ní orí èro ayélujára. A gbó wípé kò sí ...

Read More »

Òsèré Yvonne Jegede àti Oko è kí omo tuntun káàbò tí ó tún jé àkóbí won.

Gbajúgbajà Òsèré Yvonne Jegede Fawole àti oko rè dun nú nígbà tí won bí omo tuntun tí ó tún jé Àkóbí won. Bí ó ti lè jé wípé a kò tí mò bóyà ako ni àbí abo sùgbón a mò ...

Read More »

Ká ṣojú ẹni Ká sẹ́yìn ẹni Orúkọ tí à á pe ìránṣẹ́ (ìbò) .

Òtítọ́ wọn kò sí láyé mọ́ Aṣẹ̀yìn deni wọn kò wọpọ̀ Àbàtà ńlá abojú dẹ̀gun dẹ̀gun Ká ṣojú ẹni Ká ṣẹ̀yìn ẹni Àwọn mẹ́rẹ̀ẹ̀rin ní ọmọ ìkọ́fa Ilé Àgbọnnìrègún Baba kọ́won ní dídá ọwọ́ Wọ́n mọ̀ ọ́n dá Ifá kọ́won ...

Read More »

Akékòó okùnrin tí ó ti wà ní ìpelè tí ó parí ní ilé-èkó gíga polytechnic ti ìlú Oko ni won yìnbo fún tí ó sì kú.

Arákùnrin kan ni won yìn ìbon fún ní ilé-èkó gíga polytechnic ti ìjoba ní Oko ní ìpínlè Anambra. Gégé bí ìròyìn se so, olóògbé tí gbogbo èèyàn mò sí ‘ De moon’ jé Akékòó féè pari tí ó sì jé ...

Read More »

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb