Home / Tag Archives: asa yoruba

Tag Archives: asa yoruba

Ògún wa Ògún wo

Ògún wa Ògún wo

Àjàlú gbòrògàn ọkùnrin O pa ọlọ́wá sọ́wáO pa ọlọ́jà sọ́jà O pa ọkọ sí munáO pa aya ẹ sí maaroO pa àfi ọ̀rọ̀ sún ẹ sí alède gbangba Ọ̀rọ̀ Ògún lẹ mú sùn lẹ mú hanrunÒgún de ọlọ́jà èlèO bá se ọ̀wọ̀ ...

Read More »

ÌWÚRE ÒWÚRỌ̀

A kú ojúmọ́ o, a kú àsùnjí o, a sì kú ayọ́runbọ̀ di àlàyé ọkàn, àpayàn la máa pa òbí tiwa lónìí o, Ọlọ́run Elédùmarè a ṣe oore ọwọ́ ẹ̀ fún gbogbo wa bí ati ń jáde lọ síbi isẹ́ ...

Read More »
Agùnmáàníyè

Igi Agùnmáàníyè

Agùnmáàníyè ni orúkọ igi yìí, a sì máa ń lo ewée rẹ̀ fi pa kòkòrò bíi ẹ̀fọn, ìdun àti ajẹlójú-ońlé. Pẹ̀lú èyí, a kò nílò oògùn ẹ̀fọn ìgbàlódé tí ó ń ṣe àkóbá fún ìlera ara wa tí à ń ...

Read More »

Olójòǹgbòdu: The Wife of Death.

Sculpture at the Àkòdì Òrìṣà, Ile Ife, Nigeria

Read More »

Ó DỌWỌ́ ORÍ

Ó DỌWỌ́ ORÍ Gbogbo ọ̀rọ̀ ẹ̀dá dọwọ́ Orí ẹ̀ láyé; Àlámọ̀rí ọmọ ẹ̀dá ènìyàn; Ó kúkú ń bẹ lọ́wọ́ Oríi wọn gbogbo. A díá fún PMB ẹni àyànmọ́. A bù fún PYO ẹni Orí ṣe lóore. Lọ́jọ́ tí wọn ó ...

Read More »

Ẹ̀FỌN

Ẹ̀FỌN Oníyánmú ń pa yánmú, oníyànmù ń pa yànmù, Ẹ̀fọn ń se yún-ùn yún-ùn L’étí ọmọ adáríhurun. Ẹ̀fọn kìí sùn bẹ́ẹ̀ni kòní jẹ́ k’ẹ́ni orun ń kùn ó sùn. Ẹ̀fọn ń gbọ́ pà Ẹ̀fọn ń gbọ́ pò Ìjùbàlà lọ́tùn-ún Ìjùbàlà ...

Read More »
imodoye

ÌMỌ́DÒYE

An Akodi Orisa SculptureIle Ife, Nigeria January 2019Artist: Moyo Okediji

Read More »

E jowo e ran wa leti isele inu aworan yii

Eyin ara Abule, e ba ni se akiyesi aworan yii daadaa. Se kii se pe ogbeni yii fee yin ibon AK47 mo obinrin yii lapa ni? 😀 E jowo e ran wa leti isele inu aworan yii, asiko wo ni isele ...

Read More »