Home / Uncategorized / Àwon olùdáàbòbò pa àwon omo egbé ikò agbésùmòmí Boko Haram nígbà tí won d’ènà dè wón ní Borno. Àwòrán.

Àwon olùdáàbòbò pa àwon omo egbé ikò agbésùmòmí Boko Haram nígbà tí won d’ènà dè wón ní Borno. Àwòrán.

Òsùbà fún Civilian Joint Task Force (JTF) ní Gubio ìlú kan ní Borno tí won d’ènà tí won sì pa méta lára àwon ikò agbésùmòmí Boko Haram nígbà tí isé ń gbòde lówó.

Àwon olùdáàbòbò gba ìbon àti òkadà padà lówó won…

 

 

Send Money To Nigeria Free

About Awoyemi Bamimore

x

Check Also

Video Of Nigerian Prof. Austin Nwagbara That Made Ghana Sack Him