Orí ejò

Orí ejò

Bí kò bá sí ọpẹ́lọpẹ́ orí, à bá tí mú ejò digi lóko
Ìtàkùn mà lejò
Kíni yoo bá ejò ṣẹ́gun 
Orí ejò ní yoo bá ejò ṣẹ́gun 
Orí ejò

Mo sé ní ìwúre pe orí kálukú wa yoo báwa ṣẹ́gun ọ̀tá gbogbo
Akò ní di ẹran àmúso lọ́wọ́ ọ̀tá ooo

I pray for everyone of us that our head will safe us from any evil and any plans of enemy against us shall be in vain

Eu oro por todos nós que nossa cabeça nos protegerá de qualquer mal e quaisquer planos de inimigos contra nós serão em vão.

Awóyẹmí Ọlọ́run wà 1

Send Money To Nigeria Free

About ayangalu

x

Check Also

Ilé tútù

Ilé tútù

Ilé tútùỌ̀nà tútùTútù tútù là n bá ilé OluweriA dia fún Oluweri mogboojoÀtòjò AteerunIlé Oluweri kìí gbónáIlé òní gbóná mó wa Àṣẹ Ire O! Peaceful housePeaceful lifeIn peace we meet the house of OluweriIt was divined for Oluweri mogboojoCome rain or shineThe house of Oluweri is always peacefulOur homes will never be in uproar… Ase Ire O! Photo credit: Stephen Hamilton