Òkan l’ára àwon isé rè ni wípé tí ó bá ti e ò bá ti è níìfé orin rè èèyàn le níìfé àyà rè, bí kò tilè ní ìkan míràn jù béè lo, ó sáà ní àyà(6 packs) ó sì pamo jo bí edá, ó kúkú dún béè , bí ó tilè jé wípé ó pe ara rè ní “Ijele” tí àwa kò mo ìtumo rè àbi tani ó mò ó? Ó kù sí owó èyin Igbo e bá wa tu.
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more

