Home / Search Results for: Femi Akinsola

Search Results for: Femi Akinsola

Qasem Soleiman

Ẹjẹ yóó sàn, bí Amẹ́ríkà ṣe pa olórí ọmọ ogun un wa – lran

Ẹjẹ yóó sàn, bí Amẹ́ríkà ṣe pa olórí ọmọ ogun un wa..lran Kójú má ríbi , gbogbo ara lòògùn rẹ̀,bó ṣe jẹ́ pé, ó ń bọ̀ ,ó ń bọ̀ , gbogbo ara ní wọ́n mú tó o.À bí kí lọ̀rọ̀ ...

Read More »
ìrun Asham

Àwọn aláṣẹ orílẹ̀-èdè Saudi Arabia ti fòfin de kíkí ìrun Asham ní àwọn mọ́sálásí tó wà níbẹ̀

Àwọn aláṣẹ Saudi sọ pé kò ní ín sí ìrun Asham tàbí Taraweeh, ní àwọn mọ́sálásí tó wà ní ìlú Makkah àti Medina, àyàfi tí àrùn apinni léèmí coronavirus bá ti káṣẹ̀ nílẹ̀. Mínísita fún ọ̀rọ̀ ẹ̀sìn lórílẹ̀-èdè náà, Abdullateef ...

Read More »
obalufe

Ìlé ẹjọ́ rọ Obalufẹ̀ ti Ilé Ifẹ̀ lóyè

Ìlé ẹjọ́ rọ Obalufẹ̀ ti Ilé Ifẹ̀ lóyè Ìlé ẹjọ́ rọ Obalufẹ̀ ti Ilé Ifẹ̀ lóyè Fẹ́mi Akínṣọlá Ó dà bí ẹni pé awuyewuye ìfinijoyè , ìyọnilóyè sì ń tẹ̀ẹ́wájú o , bí Ilé ẹjọ́ gíga ti ìpínlẹ Ọṣun ti ...

Read More »
Osinbajo

Seyi Makinde, mo gbà fún ọ lórí ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́ tó o ṣe ní ìpínlẹ̀ Oyo—Yemi Ọṣinbajo

Seyi Makinde, mo gbà fún ọ lórí ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́ tó o ṣe ní ìpínlẹ̀ Oyo—Yemi Ọṣinbajo Fẹ́mi Akínṣọlá Ṣe wọ́n ní yini yini kí ẹni le sèmí ì ,bẹ́ẹ̀ gẹ́lẹ́ lọ̀rọ̀ rí,nígbà tíIgbákejì Ààrẹ ilẹ wa, Ọ̀jọ̀gbọ́n Yemi Osinbajo gbósùba ...

Read More »

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb