Home / Art / Àṣà Oòduà / Oko Ajagbe Eleru Leyin Jabo Lati Ori Afara Ojuelegba: Emi Awon Eniyan Ba Lo

Oko Ajagbe Eleru Leyin Jabo Lati Ori Afara Ojuelegba: Emi Awon Eniyan Ba Lo

Oko ajagbe eleru leyin kan jabo lati ori afara to wa ni Ojuelegba niluu Eko losan-an oni. Eniyan meji to wa ninu oko ti ajagbe naa jabo le lori fi ile aye sile loju-ese ti isele naa waye nigba ti awon kan fara pa koja bo ti ye.

 







About Lolade

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Meet the only survivor of the trailer accident in Ojuelegba yesterday

Presented above is Lasisi Akeem, the man in the white auto that was practically pounded by the trailer that tumbled from the bridge in Ojuelegba, Lagos yesterday September second. He figured out how to escape from his auto unhurt. He was loaded with praises Eledumare. More photographs bellow.