Home / Art / Àṣà Oòduà / Ebólo já ó dàkun
ebo

Ebólo já ó dàkun

Sẹ̀gì ni ìlẹ̀kẹ̀ ọ̀bùn à bá re ẹlẹ́gbà wọn o káwọ́

A dífá fún Ọ̀rúnmìlà baba nlọ se ọkọ Ajínàbíòkú

Ẹbọ lawo ni kí baba o se

Ifá ó to gẹ́gẹ́ kí o bámi jáwé dínà òrun mi

Ọ̀nà ikú ni kí o di

Ki o ma ma di tìfàà

Ojúmọ́ Ire ?

About ayangalu

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

ebo yoruba

Ebo: The Child Of Orunmila

Ebo is the child of Orunmila. Orunmila created Ebo on this Earth to solve the problems of human beings. People on earth use Ebo not only to solve problems but to alleviate suffering. After the sacrifice (Etutu) is made, a Babalawo will consult Ifa to ensure that it is carried to the proper place. Ebo will then invite Esu who will then take the Etutu to heaven where it will be accepted. In this way, it is not only the ...