Òtítọ́ wọn kò sí láyé mọ́
Aṣẹ̀yìn deni wọn kò wọpọ̀ Àbàtà ńlá abojú dẹ̀gun dẹ̀gun Ká ṣojú ẹni Ká ṣẹ̀yìn ẹni Àwọn mẹ́rẹ̀ẹ̀rin ní ọmọ ìkọ́fá ilé Àgbọnnìrègún Baba kọ́won ní dídá ọwọ́ Wọ́n mọ̀ ọ́n dá Ifá kọ́won ní títẹ̀ ilẹ̀ Wọ́n mò ọ́n ...
Read More »