Home / Art / Àṣà Oòduà / Ìjà ìgboro bé̩ sìlè̩ lórí Sowore
sowore

Ìjà ìgboro bé̩ sìlè̩ lórí Sowore

Ogbeni Omoyele Sowore to je aja-fun-eto- omoniyan to tun je oludije du ipo Aare ni odun yi ni o ti wa ni ahamo awon agbofinro lati bii osu meta seyin.
Ile-ejo ni ki o maa gba ile wa jejo sugbon ijoba apapo ni okan ohun ko gbee nitori okunrin naa le da ilu ru.


Ijoba apapo ni ” agbara ko lohun ko ni ile wo, sugbon onile ni ko ni gba fun un”.
Eyi lo faa ti o si se tun wa ni ahamo awon agbofinro. Awon egbe aja-fun-eto-omoniyan ti won jo wa ko fi igba kan gbagbe re. Gbogbo igba ni iwode woorowo maa n lo ni ilu Abuja ki ijoba apapo le tete mo pe inu awon ko dun si bi Sowore se tun wa ni ahamo won.


Iwode toni bi omo buruku nigba ti awon Kan naa dede jade pade won pelu Asia pe ti Buhari ni awon n se.
Ki a to wi ki a to fo awon mejeeji bere si ni tahun si ara won ki o to di pe won bere si ni tawo si ara won, ni eyi ti o mu ki awon kan bii Deji Adeyanju ati awon Kan fara pa die.

Send Money To Nigeria Free

About ayangalu

x

Check Also

Oodua Fantasy: Creatures from The Forest of No Return:

Kurekure (Ghomid) observing a (Yinmiyinmi) Dung Beetle Adeboye Adegbenro