Home / Art / Àṣà Yorùbá / Àwon apàse ilé-ìwé Obafemi Awolowo University (OAU) pàse kí won mú àwon akékòó látàrí àtakò àláfíà (peaceful protest) tí won ń se.

Àwon apàse ilé-ìwé Obafemi Awolowo University (OAU) pàse kí won mú àwon akékòó látàrí àtakò àláfíà (peaceful protest) tí won ń se.

Ogbà Obafemi Awolowo University (OAU) ti kó sí inú dàrúdàpò nígbà tí òpò akékòó tò lo sí àgó olóòpá tí ó wà ní Moore ní ìlú ile-ife láti bèèrè fún ìdásílè àwon akegbé won tí àwon ìgbìmò ìdábòbò Ogbà náà ti mú, tí won sì ti tì wón mó àgó olóòpá tí ó wà ní Moore .

Ó máa wà nínú àkosílè wípé ní ojó kàrún osù kewàá odún 2017 (5/10/2017) ni àwon akékòó se àtakò àláfíà látàrí ohun èlò tí kò sí ní inú Ogbà. Ní ojó kejì àtakò yí, àwon ìgbìmò ìdábòbò ilé-èkó yí sáré lo sí ààrin àwon akékòó yí tí won sì mú méwàá nínú won, tí igbákejì ààre akékòó ifáfitì yí “Jacob Tosin(Emerald)”sì wà láàrin won…

Send Money To Nigeria Free

About Awoyemi Bamimore

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Alao Akala, Funke Adesiyan, Teslim Folarin àti àwon míràn ní won fi egbé alásìá tí a mò sí PDP sílè lo sí egbé oní ìgbálè tí a mò sí APC.

Baba ìsàlé egbé APC tí a mò sí asíwájú Bola Ahmed Tinubu, Gómìnà ìpínlè Osun tí a mò sí ògbéni Rauf Aregbesola, Gómìnà ìpínlè Ondo, tí a mò sí Rotimi Akeredolu ní ìlú Ibadan ti fi tòwòtòwò gba olóyè Alao Akala, òsèré Funke Adesiyan, Teslim Folarin àti àwon míràn láti inú egbé PDP sí egbé APC.