Home / Art / Àṣà Oòduà / Àwòrán télè ti Leo Babarinde Dasilva nígbà tí ó wà ní omo àgbákórùn.

Àwòrán télè ti Leo Babarinde Dasilva nígbà tí ó wà ní omo àgbákórùn.

Àwòrán télè ti Leo Babarinde Dasilva nígbà tí ó wà ní omo àgbákórùn.
Ní àná tí se ojóbò tí àwon eléyìbó n pè ni Thursday, won ni kí àwon wo èyìn wò.
Ará ilé BBNaija télè tí a mò sí Leo Babarinde Dasilva náà wo èyìn wò nígbà tí ó pín àwòrán ìgbà èwe rè sì orí èro ayélujára insítágírámú.

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

taniolohun

Esin Ajeji Pelu Ete