Home / News From Nigeria / Breaking News / Àwòrán tuntun tokotayà tí won sèsè fé ara won léyìn tí won ti wà gégé bí Òré tímótímó.

Àwòrán tuntun tokotayà tí won sèsè fé ara won léyìn tí won ti wà gégé bí Òré tímótímó.

Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbeyàwó olùgbá bóòlù aláwòn ní Brooklyn, Quincy Acy àti àfésónà rè, Jessica Fuenten tí ó sèsè gbòde kan léyìn ìgbà tí inú arewà ìyàwó àfésónà sì ń dùn, so wípé àwon bèrè gégé bíi Òré tímótímó. Àtìgbà tí àwon ti fé ara àwon, àwon ń gbé pèlú ìdùnú gégé bí a ti ri nínú àwòrán ìsàlè yìí. E wo irú ìdùnú tí omobìnrin yí kò bá pàdánù tí kò bá gbà kí won fé ara won sùgbón tí won jo jé Òré Lásán …

Send Money To Nigeria Free

About Awoyemi Bamimore

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

Enter Captcha Here : *

Reload Image

x

Check Also

Àwòrán ìsìnkú Tagbo Umueke ní ìpínlè Anambra .

      Òré Davido, tí ó n jé Tagbo Ifeatuchukwu Umueike ni ó sùn re ní ogún’jó osù kèwá odún, 2017 (20/10/2017) ní ìlú tí a bi sí. Ní ìjoba ìbílè Osumenyi ní ìpínlè Anambra .    Àwon òré àti aféniféni ni won péjú p’ésè níbè láti fun ní ìbòwò ìkeyìn tí ó jé wípé àwon olùdábòbò sì n se ìwádìí ikú tí ó pa á….