Home / Art / Àṣà Yorùbá / Àwòrán Kí Ó Tó Di Ojó Ìgbeyàwó Láàrin Eléyàmeyà

Àwòrán Kí Ó Tó Di Ojó Ìgbeyàwó Láàrin Eléyàmeyà

Omo Ooduarere tún gbé tuntun dé ooo, àwòrán kí ó tó di ojó ìgbeyàwó láàrin eléyàmeyà. Femi (yorùba) àti Mma rè tí ó ń jé OGECHI láti (River), inú won dùn púpò gan bí won se ya àwòrán papò nínu aso a-lá-rà-n-ba-rà….

Orísirísi àwòrán sì wolé léyìn ìjáde won…


English version

Continue after the page break

Send Money To Nigeria Free

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

Enter Captcha Here : *

Reload Image

x

Check Also

ado awaye

Odó kàyééfi ńlá tí ó wà ní *ADO AWAYE*.

Ìlú kéréje kan wà ní ìpínlè Oyo tí orúko ìlú náà sì ń jé *ADO AWAYE*, òdó kàyééfi kan wà ní ìlú yí tí ó jé wípé bí ènìyàn bá ti esè kan bo inú rè yóò fa eni náà tí a kò sì ní mo ibi tí eni náà ma jásí. Bí ènìyàn bá bu omi òdó yí tí ó se àdúrà si tí ó sì mun-ún gbogbo ohun tí ó bá toro ni yóò rí béè. Orúko odò ...