Home / Art / Àṣà Yorùbá / Eewo orisa iyawo-aare orile-ede fe nan owo si alafin
aisha buhari

Eewo orisa iyawo-aare orile-ede fe nan owo si alafin

Aaa eewo orisa iyawo-aare fe nan owo si alafin sugbon alafin ko(refuse) o kare baami iku babayeye gbogbo eni toba bami ri aisha buari iyawo aare orile-ede wa e bami sofun pe awa ki duro ki oba a ki bere ki oba beni aki bo oba l’owo(hand-shake) ayafi ti oba ba fe, idobale la ki oba. Aisha-buari e ma san iru aso be soro mo, e ma gbiyanju lati sope e fe ba iku baba-yeye bo-owo(hand-shake) agbedo ka ma ri, bi e ba nse be fun emir-kano, e ma dan iru re wo nile yoruba. ojulu emi o ni ki akalolo ma ke ewi sugbon koma k’ewi ki baba to bi mi l’omo. a bi kileni mowi gbogbo eyin ojulowo ooduarere te mo itumo asa (culture)?

Send Money To Nigeria Free

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

The Alaafin(s) of Oyo: Iku baba yeye alase keji Orisa.

REIGNS OF THE ALAAFINS OF OYO and SOME HISTORICAL MARKS   892 Oranyan – Oyo-Ile was found 1042 Ajaka Dada 1077 Tella Oko –known as Sango Afonja 1137 Ajaka 1177 Aganju Sola 1300 Kori – Osogbo and Ede were found Continue reading after the page break