Home / Art / Àṣà Oòduà / Gómìnà Nyesom Wike dá òkan lára àwon Konmisôna rè dúró. 
gomino

Gómìnà Nyesom Wike dá òkan lára àwon Konmisôna rè dúró. 

Gómìnà ìjoba ìpínlè River, Nyesom Wike ní òwúrò yí dá Konmisôna isé dúró ní ìpínlè rè tí orúko rè ńjé Bathuel Harrison (àwòrán eni tí ó wo jákèètì).  Nínú òrò tí olùrànlówó pàtàkì rè so lórí ìtànná ohun Ìgbéròyìn jáde (Electronic media), Simeon Nwakaudu. Wike so wípé ìdádúró náà esèkesè ni; ó so fún Harrison kí ó gbé ipò fún Akòwé pípé nínú àkóso náà. Kò sí ìdí kan pàtàkì tí won fi lé Konmisônna na níbi isé….

English Translation
Continue after the page break

About ayangalu

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

taniolohun

Esin Ajeji Pelu Ete