Home / Art / Àṣà Oòduà / Nje Iwo Tiri Iru Igbeyawo Eleyi Ri ?

Nje Iwo Tiri Iru Igbeyawo Eleyi Ri ?

Ni ile aye tabi kani ni Nigeria wa yi orisirisi lama ma ri. Ni Nigeria wa yi na loti sele, O’ku osu meji ti awon toko taya yi dajo Igbeyawo won ni Oko Iyawo wan ni atimole awon olopa ni ilu Oyinbo, ni iyawo bani awon ti dajo Igbeyawo awon o si leyi ojo na pada, pe sis niohun ma se Igbeyawo ohun,won si se Igbeyawo na osi larinrin  pelo (pic) oko iyawo,Hunnnnmm orisirisi lohun sele laye.

 

Send Money To Nigeria Free

About admin