Home / Tag Archives: Iwure (page 2)

Tag Archives: Iwure

Yoruba Festival

Iwure Owuro Toni: 24-04-2016

E MAA WI TELE MI : …… *Ade ogo mi ko ni si danu. *Aso iyi, aso eye mi ko fa ya. *Edumare ma je ki n fi ota se ore. *Oluwa dakun so egan mi dogo. *Edumare wa so ...

Read More »
iwure

Iwure Owuro – 09/04/2016

E MAA WI TELE MI : ………. *Edumare pase irorun sinu aye mi. *Oluwa tanmole si ogo aye mi. *Eni to n se atako ire aye mi, Oluwa f’eje re setutu ola mi. *Oluwa gbe alaanu dide si mi. *Pasan ...

Read More »

Iwure Owuro 21/03/2016

E MAA WI TELE MI : …….. *Aye ko ni gbe ounje mi fun aja je. *Atije-atimu mi ko ni nira. *Oluwa so egan mi dogo. *Aye ko ni ta epo s’aso ala mi. *Fitila ogo mi ko ni ku. ...

Read More »
Odu ifa otura meji

Odu Ifa Otura Meji: Ifa Effective Iwure Against Litigation (PRAYER)

This iwure ( prayer) which is derived from Odu ifa otura meji is highly recommended and good for any body who have litigation or law suit or any issues relating to case or offence. The vehement recital if this verse ...

Read More »
iwure

Iwure Eyonu Awon Agba

Edumare,Oba Ajiki,Ajige,Oba toto bi aro. Awa dupe lowo re ,pe o yo nu si wa lati atete ko se titi di oni oloni. Jowo Baba Alanu ,masai ko Anu re kuro Lori wa (mi). Jowo Baba ologo lola ,je ki ...

Read More »