Home / Art / Ifa physiology: Ojú/Eyes

Ifa physiology: Ojú/Eyes

Ojú.
Ojú lalákàn fi í sọ́rí.
Ojú oró ní í lékè omi.
Ojú ò ní tì wá lótù Ifẹ yìí láíláí.
Ojú ò níí relé de ìkankan nínú àwa ọmọ Awo.

Eyes–Oju
With the eyes, the crab watches the ori.
Oju oro stays atop standing waters
Oju will not disgrace us in Oju Ife
Oju will not depart from all of us siblings of Awo

Send Money To Nigeria Free

About admin

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Gbogbo oju to nwo aworan yi…

Gbogbo oju to nwo aworan yi eni wole aisan won ni tayin lofa aburu ooo ao ni ri ogun ada njinan ooo !! Ase !