Home / Naija Gist / Metro life / “ALAAFIN PE 77!” – Kehinde Ayoola J P
alafin oyo

“ALAAFIN PE 77!” – Kehinde Ayoola J P


Olori ile igbimo asofin ipinle Oyo nigba kan ri, ogbeni Kehinde Ayoola J P ti ranse ikini si Oosa ilu Oyo, Oba Lamidi Olayiwola fun ayeye ojo ibi baba to ko layo.

Oro ikini ogbeni Ayoola ni yii:

“Baba wa, Oba Dr Alhaji Alhamis Olayiwola Atanda Adeyemi, ALOWOLODU III, JP, CFR, LLD , Alaafin ti ile Oyo pe eni odun
metadinlogorin (77) lonii.

Ki ade pe l’ori, ki bata pe l’ese, ki irukere k’o di abere ati pe kiesin oba k’o je oko pe o. Igba ile k’o nii fo, beeni awo ile k’o
nii fa ya o.

Kabiyesi, ase ti e n pa fun oyinbo ti oyinbo n gbo, ase naa ko nii tan o.

Eyi tee pa fun ologun ti won gbo, ase
naa o nii tan o. Eyi tee si n pa fun awon oloselu ti won n gbo, ase ohun o nii tan.
Kabiyesi iku baba yeye, igba odun, odun kan ni o!

Emi yoo se opo re laye. Ase !! “.

Send Money To Nigeria Free

About admin

x

Check Also

business gist

A giant ship’s engine; Expertise and experience, that’s expensive.

A giant ship’s engine broke down and no one could repair it, so they took it to a Mechanical Engineer with over 40 years of experience.He inspected the engine very carefully, from top to bottom. After seeing everything, the engineer unloaded the bag and pulled out a small hammer.He knocked something gently. Soon, the engine came to life again. The engine has been fixed!7 days later the engineer mentioned that the total cost of repairing the giant ship was ₦6,140,000 ...