Home / Art / Àṣà Oòduà / Aalo apamo Toni: Itan aja ati ijapa!
aloo apamo aja ati ijappa

Aalo apamo Toni: Itan aja ati ijapa!

Alo ooooooo, alo oooooooo. Itan aja ati ijapa. Ni ojo kan iyan mu ni ilu kan, ko si onuje, baba agbe kan wa, to je ipe ohun ni kan ni o gbin n kan si oko re. Ti awon ara ilu ma fi n ri onuje je.

Ni ojo kan ijapa lo ba aja ni ile o ni ki awon lo wa onuje ni oko. Igba ti won de oko aja wu isu ti agbara re le gbe, sugbon ijapa se oju kokoro o wu isu ti ko le da gbe, o wa n pariwo ipe aja diro ran mi leru, feren ku fen, ti o ba duro ran mi leru, feren ku fen, ma ki gbe oloko agbo, agbo o agbewade ferenkufe.

Bi oloko se ka ijapa mo oko ni yi o. O di ile oba, won bere ni owo ijapa o ni ohun ati aja ni won jo lo. Oba pase ipe ki won lo mu aja wa. Igba ti won de ile aja, o ti da ina o ti n ya ina o ti fi epo pupa para, o di eyi si ireke otun ati osi. Won mu de ile oba , o se bi eni ti are ti mu ni ojo meta. Won ni ki aja soro se ni o n po.

Oba ni se eni ti are n se yi lo mu iwo ijapa lo si oko oloko, won ni ki aja ma lo si ile re ni ayo ati alafia. Won ni ki won lo ti irin gbigbona bo inu ina ki won ti bo ijapa ni idi ki o yo ni ori re. Bi won se pa ijapa ni yi o. Ki ni itan yi kowa.

About admin

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Aalo apamo – Mayaki Ojo

Aalo apamo Obi awe kan aje de oyo, baba kukuru de fila bentigo, kini nboba jeun ti kii mu sibi dani? Aguntan baba mi kan lailai, aguntan baba mi kan lailai, owoo ni nje kii je agbado. ( Ahon, oko, esin-sin, Obinrin) happy xmas ni gbogbo kaaro oojire.