Home / Art / Àṣà Oòduà / Alex Asogwa di onílè púpò ní Omo odún méjìlélógún (22).

Alex Asogwa di onílè púpò ní Omo odún méjìlélógún (22).

Ará ilé Big Brother Naija télè tí a mò sí Alex Asogwa tí ó sèsè towó bo ìwé pèlú ilé-isé tí ó n ta ilè tí ó tún ń ta Ilé, ilé-isé real estate and investment company.Alex Asogwa ti gbe lo sí orí èro ayélujára láti dúpé lówó olórun, nítorí kìí se onílè eyo kan bí Kò se púpò, nígbà tí Kò sì ju omo odún méjìlélógún Lo.

 

About Awoyemi Bamimore

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

taniolohun

Esin Ajeji Pelu Ete