Home / Art / Àṣà Oòduà / Odu Ifa Owonrinsindin/edi
Orisa IFA movement

Odu Ifa Owonrinsindin/edi

| | |
| | | |
| | |
| |

 

Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, eledumare yio pin ere kanwa o, ayo ojo oni koni fiwa sile o ase.
Odu ifa OWONRINSINDIN/EDI lo gate laaro yi, ifa yi gba akapo ti odu ifa yi ba jade si niyanju wipe ki o bo Oluweri daradara, ifa ni akapo yi nfoju ekun nserahun ire gbogbo, sugbon ti o ba le bo Oluweri yi, ifa ni Oluweri yio si ona ire gbogbo fun yio si di oloro eniyan.
Ifa naa ki bayi wipe: Ipa ti a pagba naa ni a se pa akeregbe a difa fun Oluweri lojo ti nfoju ekun nserahun ire gbogbo won ni ko karale ebo ni ki o wa se ki o baa le ni ire gbogbo laye, obi ifin meji, eyele funfun 16, ekuru funfun, Opa aso funfun 16, otin ati igba ewe ayajo ifa Oluweri kabomora Oluweri rubo won si se sise ifa fun, nigbati o maa di ale, Oluweri sun o la ala ri alaso funfun nigbati o wa di aaro ojo keji o gbera o dile Orunmila o si salaye ala ti o la fun baba, Orunmila wa ni ire re ti de pe etutu re ti gba lotito ko pe ko jina Oluweri dalaje o dolokun o donide o la gboo bi ile ere okin o wa njo o nyo o nyin awo awon awo nyin ifa, ifa nyin eledumare oni nje riru ebo a maa gbeni eru arukesu a maa da ladaju ko pe ko jina ifa wa bami ni jebutu ire nje jebutu ire ni a nba awo lese obarisa.
Eyin eniyan mi, mo gbaladura laaro yi wipe Oluweri yio pese oro aye fun wa, ako ni se alaini ohun rere laye, ile wa yio maa kun fun idunnu ati oro nigba gbogbo ni, ala rere ti a n la yio se mowa lara o aaaseee.
ABORU ABOYE OOO.

 

English Version: 

Good morning my people, how was your night? Hope you are well slept, may the joy of today never depart from us amen.
It is OWONRINSINDIN/EDI corpus that revealed this morning, ifa advised whoever this corpus revealed out for to offer sacrifice for Oluweri, ifa said he/she lack financially but if he/she can offer Oluweri a proper sacrifices, he/she would be bless abundantly by Oluweri. Also, Oluweri should be worship as his/her orisa of the corpus.

 

Hear what the corpus said: ipati a pagba naa ni a se pa akeregbe it cast divined for Oluweri when she was weeping that she didn’t have goodnesses, she was advised to offer sacrifice, two white kola nuts, white pigeon 16, white cloth 16yrd, gin, and ifa leaves and she complied also ifa medicine was done for her, when it was night Oluweri slept and dreamt of someone that wore full of white cloth, when she woke up on the second day she went to narrated what she saw on the dream to Orunmila and Orunmila told her that her sacrifice has been accepted because what she saw on her dream was goodnesses, aftermath Oluweri became rich plentifully and she have all good things in her house, she started dancing and rejoicing praising priest the priests were praising ifa while ifa was praising God.

 
My people, I pray this morning that Oluweri will bless us abundantly, may we never lack of any good things, our house will full of treasure and happiness, our good dreams will manifest in our life amen.

 

Faniyi David Osagbami

About ayangalu

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Òrìṣà is Òrìṣà.

Olódùmarè is Olódùmarè and Òrìṣà is Òrìṣà.

Olódùmarè is not God.Olódùmarè is Olódùmarè.There are no temples to Olódùmarè.Òrìṣà is Òrìṣà.Òrìṣà does not translate to a god or goddess.The emissaries of Olódùmarè here on earth to do the will and work of Olódùmarè are called the ÒRÌṢÀ.Olódùmarè is neither male nor female.Olódùmarè is gender-neutral.Olódùmarè has neither liturgy nor any iconography.I have not seen where Olódùmarè is begging or threatening for love or acceptance.Our own Olódùmarè is not jealous. Olódùmarè doesn’t need to kill thousands of people to just ...