Home / Art / Àṣà Oòduà / Olópàá kan ní orílè èdè Ghana fi pàsán na arábìnrin yí ní ìdí nítorí ó kò láti w’onú èwòn .

Olópàá kan ní orílè èdè Ghana fi pàsán na arábìnrin yí ní ìdí nítorí ó kò láti w’onú èwòn .

    Olópàá tí ó n sojú àgó olópàá Domping ní orílè èdè Ghana, Ase Emmanuel Osei ni won ti fi èsùn kàn látàrí wípé ó fi pàsán na arábìnrin odún mókàndílógbòn (29) tí a mò sí Sarah Darko ní ìdí látàrí ó kò láti wo inú èwon.

About Awoyemi Bamimore

One comment

  1. LALAKUKULALA Refix

    Oye Kiwon Ran Olopa Yen Lo Si Ewon Ni.
    Iwa radarada Ni ogbeni Yii wu

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti