Lẹ́yin ọdún mẹ́ta lílọ bibọ̀ lórí ọ̀rọ̀ Brexit, ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́ṣì padà kúrò lábẹ́ EU ní aago mọ́kànlá alẹ́ ọjọ́ Jimọ ọjọ́ kọkànlélọ́gbọ̀n Oṣù kínní ọdún 2020.
Read More »Odù kan gorí àtẹ,Ọdẹ́gbèmí Ọdẹ́gbolá11 goróyè Àràbà nílẹ̀ẹ̀bàdàn
Odù kan gorí àtẹ,Ọdẹ́gbèmí Ọdẹ́gbolá11 goróyè Àràbà nílẹ̀ẹ̀bàdàn Fẹ́mi Akínṣọlá Erin wo! Àràbà Awo ilẹ̀ Ìbàdàn, Ògbó Awo Oyewusi Amọo Fakayode wọ káàl’ẹ̀ sùn.Ọjọ́ a kú là á dère,èèyàn ò sunwọ̀n láàyè. Bí àlá ló ń ṣe ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ẹni ...
Read More »Should any man remain entitled to be intimate with women, after flatly denying latter the power to become Ifa diviners?
Should women be allowed to practice as Ifa diviners?(Actually, what sort of stupid question am I asking?Who appointed men as the gatekeepers regulating what women should or should not do?)The proper question is this: should any man remain entitled to ...
Read More »Ìkòkò Ọ̀ṣun, Àkòdì Òrìṣà
Orisa Artists building a gigantic ikoko (pot) of Osun, at the Akodi Orisa, Ile Ife, Nigeria. Ìkòkò Ọ̀ṣun, Àkòdì Òrìṣà
Read More »O lè wọ sòkòtò tó tóbi, ṣùgbọ́n kò sí ààyè fún yẹ̀rì,láti sìnrúùlú …Àjọ àgùnbánirọ̀. (NYSC)
O lè wọ sòkòtò tó tóbi, ṣùgbọ́n kò sí ààyè fún yẹ̀rì,láti sìnrúùlú …Àjọ àgùnbánirọ̀. (NYSC) Fẹ́mi Akínṣọlá Ọ̀gá àgbà fún àjọ àgùnbánirọ̀ lórilẹ̀-èdè Nàìjíríà, Brig. Shuaibu Ibrahim ti sàlàyé fún akọ̀ròyìn pé ààyè wà fún àgùnbánirọ̀ tó bá fẹ́ ...
Read More »N kò leè fi ìdúnú mi pamọ́ lọ́jọ́ ìkómọ àwọn ìbẹta….Yinka Ayefele
N kò leè fi ìdúnú mi pamọ́ lọ́jọ́ ìkómọ àwọn ìbẹta….Yinka Ayefele Fẹ́mi Akínṣọlá Ẹ̀dá ò láròpin láyé, ṣé bí ó se wu Olúwa Ọba níí sọlá, fẹ́ni Ó wù ú,bẹ́ẹ̀ gẹ́lẹ́ ni ọ̀rọ̀ níbi tí t’ọba, tìjòyè, ọ̀tọ̀kùlú ìlú ...
Read More »Lai Mohammed fa o̩mo̩ Naijiria létí lórí ìròyìn òfegè
Lai Mohammed fa ọmọ Nàìjíríà létí lórí ìròyìn òfegè Fẹ́mi Akínṣọlá Mínísítà ètò ìbáraẹnisọ̀rọ̀ àti Ìròyìn lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Lai Mohammed ti ní ìjọba yóò bẹ̀rẹ̀ ṣí í ṣe àmójútó àtagbà ojú òpó ayélujára báyìí.Ìgbésẹ̀ yìí ni láti ṣe àfọ̀mọ́ ojú ...
Read More »Vietnamni , ẹ wá dá oko ìrẹsì sílẹ̀ ní Nàíjíríà, dípò kíkórẹsì wọlé– Oshiomole fèsì ẹ̀bẹ̀
Vietnamni , ẹ wá dá oko ìrẹsì sílẹ̀ ní Nàíjíríà, dípò kíkórẹsì wọlé– Oshiomole fèsì ẹ̀bẹ̀ Fẹ́mi Akínṣọlá Bí Ìjọba Nàíjíríà se gbé àwọn ẹnu ọ̀nà àbáwọlé sí orílẹ̀ -èdè yìí tìpa ti ń mú kí orí ta àwọn lórílẹ̀-èdè ...
Read More »Atiku tún pàdánu nílé e̩jó̩ tó ga jù
Atijo tun padanu nile ejo to ga juLati owoYinka AlabiIle-ejo to ga ju lo ni orileede yii ti se idajo lori ejo ti oludije dupo Aare ni abe egbe oselu PDP, Alhaji Atiku Abubakar.Ile-ejo ni Aare Muhammadu Buhari naa ni ...
Read More »Akpabio fajúro sí owó ìnákúùná Niger Delta
Akpabio fajuro si owo inakuna Niger DeltaLati owoYinka AlabiIjoba apapo ti Senato Akpabio n soju fun lo ti gbanaje lori awon ise ajanbaku to n waye ni agbegbe Niger Delta. Akpabio ni o ye ki ise ijoba maa te siwaju ...
Read More »