Home / Art / Àṣà Yorùbá / Egbe APC Kogi ti yan oludije gomina tuntun
apc

Egbe APC Kogi ti yan oludije gomina tuntun

Leyin gbogbo rukerudo oselu to ti n sele nipinle Kogi, eleyii to bere leyin iku Abubakar Audu, awon egbe APC ti yan Yahaya Bello gege bi eni ti yoo ropo Audu to ku. Ogbeni James Faleke naa si ni won fe lo gege bi igbakeji re. Sugbon titi di akoko yii, a ko le ti so boya Faleke faramo aba lati di igbakeji okunrin naa.

Send Money To Nigeria Free

About admin

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

Enter Captcha Here : *

Reload Image

x

Check Also

Òdómobìnrin odún mókàndínlógún pín àwòràn ilé tí ó rewà tí sugar daddy rè rà fun .

      Òdómobìnrin odún mókàndínlógún tí ó tún jé ò n lò èro ayárabíàsá (Twitter) ti gba àwon òdóbìnrin ní ìmòràn wípé kí won múra sísé kí won sì gbàgbó nípa èróngbà olórun sí won nígbà tí ó n fi ilé bògìnì tí sugar daddy rè gbà fun hàn . Nígbà tí enìkan bi lérè wípé sé ó ti fi sugar daddy rè sílè, rí ó sì dáhùn wípé rárá …