Ilé tútù

Ilé tútù

Ilé tútù
Ọ̀nà tútù
Tútù tútù là n bá ilé Oluweri
A dia fún Oluweri mogboojo
Àtòjò Ateerun
Ilé Oluweri kìí gbóná
Ilé òní gbóná mó wa

Àṣẹ Ire O!

Peaceful house
Peaceful life
In peace we meet the house of Oluweri
It was divined for Oluweri mogboojo
Come rain or shine
The house of Oluweri is always peaceful
Our homes will never be in uproar…

Ase Ire O!

Photo credit: Stephen Hamilton

Send Money To Nigeria Free

About ayangalu

One comment

x

Check Also

corona

Èsì àyẹ̀wò tuntun Nàìjíríà fihàn pé “313” èèyàn ti gbàlejò Kofi 19 …àjọ NCDC

Èsì àyẹ̀wò tuntun Nàìjíríà fihàn pé “313” èèyàn ti gbàlejò Kofi 19 …àjọ NCDC À fi kí á bẹ Ọlọ́run kó bá wa dásí ọ̀rọ̀ àjàkálẹ̀ àrùn ajániláyà pàtì yìí, bí àwọn tó ní kòrónáfairọ̀ọ̀sì ní Nàìjíríà ti ń peléke sí i báyìí,lẹ́yìn tí àjọ NCDC tún kéde okòólélọ́ọ̀dúnrún dín méje èèyàn tí èsì àyẹ̀wò wọn sẹ̀sẹ̀ jáde. Ní báyìí, èèyàn ẹgbẹ̀rún méje, àti . òjìlélẹ́gbẹ̀rin dínkan (7839) ni àkọsílẹ̀ wà pé ó ti ní àrùn náà ní Nàìjíríà. Àkójọpọ̀ ...