Home / Author Archives: admin

Author Archives: admin

Olojo Ibi

Mo layo lati so fun yin wipe oni ni ojo ibi mama wa TUNRAYO IBRAHIM ti won je okan pataki ninu ebi Oodua Rere. Iyalode olojo ibi a ki yin e ku ayo oni, e o se pupo re laye ...

Read More »
aso iyi ile yoruba

Ojuitere ooooooo!!

mo de werewere bi eji-ale mo de warawara bi ti iyaleta, ewe-itu lo ni ke tu mise ewe-iifa loni kefa mi mora, toripe enikan ki so okun mo igbin lorun, won ki fi pakute mu eja l’odo, beni omode koni ...

Read More »