Home / Art / Àṣà Oòduà / Àwọn obìnrin tọ́kasí pàtàkì ìbáraẹnidọ́gba láárin ọmọnìyàn
naija gist ladies

Àwọn obìnrin tọ́kasí pàtàkì ìbáraẹnidọ́gba láárin ọmọnìyàn

Àwọn obìnrin tọ́kasí pàtàkì ìbáraẹnidọ́gba láárin ọmọnìyàn

Ọjọ́ kẹjọ ọdọọdún ni àyájọ́ àwọn obìnrin lágbàáyé níbi tí gbogbo àgbáyé tí ń kọjú sí àwọn obìnrin láti yòǹbó àwọn iṣẹ́ takuntakun tí wọ́n gbé ṣe láì nọ́ọ́ní onírúurú ìpèníjà, ẹ̀dùn ọkàn àti Ìlàkàkà wọn fún àṣeyọrí gbogbo
Ẹ̀tọ́ àwọn obìnrin pẹ̀lú ìdọ́gba pẹ̀láwọn ọkùnrin ló gbòde gẹ́gẹ́ bíi ohun òjútáyé lásìkò àjọyọ̀ àyájọ́ obìnrin lágbàáyé ti ọdún yìí.

Àkọmọ̀nà àyájọ́ náà fún ọdún yìí ni “ajàfẹ́tọ̀ ìbáradọ́gba ni : mímú ẹ̀tọ́ àwọn obìnrin ṣẹ.”

Nínú ọ̀rọ̀ tiwọn, àjọ ìṣọ̀kan àgbáyé rọ àwọn èèyàn gbogbo láti jí gìrì gbógun ti àwọn ìpèníjà sísọ àìdọ́gba láàrin ẹ̀yà ẹ̀dá gbogbo.

Nínú ọkàn ò jọ̀kan ọ̀rọ̀ tí wọ́n ṣọ ní ìrántí àyájọ́ yìí, àwọn obìnrin ní oríṣìríìṣí Ìlànà iṣẹ́ ajé gbogbo sọ̀rọ̀ lórí ìpèníjà tí wọ́n ń dojúkọ; paàpá jùlọ láàrin àwọn ọkùnrin lẹ́nu iṣẹ́ ajé gbogbo léyìí tí ò jẹ́ adínàgboòkú.

Fẹ́mi Akínṣọlá

Send Money To Nigeria Free

About ayangalu

x

Check Also

Ògún Majek wọ káà ilẹ̀ sùn

Ògún Majek wọ káà ilẹ̀ sùn Ọlọ́jọ́ ń kajọ́, ẹ̀dá ò fiyè si.Ìjọ ọmọ tuntun dáyé, nijọ́ ìdùnnú, ẹ̀rín, òhun ọ̀yàyà fún ẹbí,ará, pẹ̀lú ìyekan. Ṣùgbọ́n kìí rọgbọ ká sàdédé sàfẹ̀kù èèyàn ẹni pékú yọwọ́ ọ rẹ̀ ní dúníyàn. Àsamọ̀ yìí ló díá fún ìròyìn tó ń tẹ̀ wá lọ́wọ́ báyìí pé, ìlúmọ̀ọ́ká òṣèré tíátà Gbọ́lágadé Akínpẹ̀lú, tí ọ̀pọ̀ èèyàn mọ̀ sí Ogun Majek ti jáde láyé, bákan náà wọ́n ti sin-ín ní ìlànà mùsùlùmí. Ọ̀rẹ́ tímọ́timọ́ Ògún Majek tí ...